Bàbá Àjàyí

Ọkùrin gban-gban bíi ọjọ kan orí.

Ọmọ arówó seré nì ìdí àpè, ọmọ ò toko bọ̀ ṣe bíi ọba.

Bàbá Àjàyí ṣetán láti lo àǹfàní tí ó bá yọ láti fi ẹwà èdè àti àṣà Yorùbá kọ́ Àjàyí àti àwọn ọmọdé ìyókùn.