Ìyá Àjàyí

Ọlọ́gbọ́n, oníwàpẹ̀lẹ́.

Ọmọ afínjú ẹyẹ ádàbà tí ńjẹ láwùjọ òrófó.
Ọmọ afínjú ẹyẹ tí ńjẹ ní ìta gbangba.

Àjàyí ṣe oríire púpọ̀ láti ní ìyá tì o dára jùlọ nì gbogbo ayé. O ṣetán ní gbogbo ìgbà láti ṣe ìtọ́jú Àjàyí àti láti kọ́ọ ní ìwà tì ó dára gẹ́gẹ́ bíi ọmọlúàbí.