Wesley Lowe

Ọ̀gbẹ́ni Wesley Lowe ti ńya àwòrán fún ìwé àwọn ọmọdé láti bíi ogún ọdún sẹ́yìn. Bákannáà, ó tún ńya àwòrán fún àwọn ìwé oriṣi míràn. Ó ńya awọn àwòrán wọ̀nyí pẹ̀lú ìmọ̀ ẹ̀rọ digital tàbi àfọwọ́yà ti àtijọ́.