Àjàyí gbọ́ ìtumọ́ ìlù wà ní Amazon.com (.uk, .ca) àti Barnes and Noble. Ẹ tún le béèrè fún ìwé yí ní ilé ìkàwé àdúgbò yìn. Ẹ fi àpèjúwe ìwé yǐ wá a:
Àjàyí gbọ́ ìtumọ̀ ìlù | |
akọ̀wé: | Fọlákẹ́ Ọládoṣù |
ayàwòrán: | Wesley Lowe |
ilé iṣé akọ̀wé: | Adubi Publishing |
ọjọ́ ìjáde: | Oṣù kọkànlá, 2013 |
ISBN: | 0986643513, 978-0986643514 |
ojú ewé: | 34 (mẹ́rìnlélọ́gbọ̀n) |
àwọn tí a ṣe ìwé fún: | Ọmọ ọdún mẹ́rin sí mẹ́sǎn |
Ẹ kọ̀wé sí Àdùbí ní: