Fọlákẹ́ Olàdoṣù

A bí Fọlákẹ́ nì apá ìwọ̀ oòrùn orílẹ̀ èdè Nigeria. Òǹkọ̀wé ṣe ìwé yǐ nì ìbámun pẹ̀lú ìmọ̀ ẹ̀rọ tuntun fún àwọn òǹkàwé òde òní.

Èròǹgbà làti kọ ìwé yǐ bẹ̀rẹ̀ ní bíi ọdún mélǒ sẹ́yìn nígbàtí ọmọ òǹkọ̀wé yǐ bẹ̀rẹ̀ síí ka àwọn ìwé ọmọdé tí a kọ ní èdè Òyìnbo. Kò sí irú àwọn ìwé báyǐ ni èdè Yorùbá, pàá-pàá jùlọ ní òkè Àríwá America.